Òwe 2:20
Proverbs 2:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere kí ìwọ kí ó sì pa ọ̀nà àwọn olódodo mọ́.
Proverbs 2:20 in English
Proverbs 2:20 · Berean Standard Bible
So you will follow in the ways of the good, and keep to the paths of the righteous.
Context
18Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikú
ipa ọ̀nà rẹ̀ sọ́dọ̀ àwọn òkú. 19Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padà
bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í dé ọ̀nà ìyè. 20Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere
kí ìwọ kí ó sì pa ọ̀nà àwọn olódodo mọ́. 21Nítorí ẹni dídúró ṣinṣin yóò gbé ní ilé náà
àwọn aláìlẹ́gàn sì ni yóò máa wà nínú rẹ̀. 22Ṣùgbọ́n a ó ké ènìyàn búburú kúrò lórí ilẹ̀ náà
a ó sì fa àwọn aláìṣòótọ́ tu kúrò lórí rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.