Òwe 2:19
Proverbs 2:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padà bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í dé ọ̀nà ìyè.
Proverbs 2:19 in English
Proverbs 2:19 · Berean Standard Bible
None who go to her return or negotiate the paths of life.
Context
17ẹni tí ó ti kọ ọkọ àkọ́fẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ sílẹ̀
tí ó sì gbàgbé májẹ̀mú tí ó ti dá níwájú Ọlọ́run rẹ̀. 18Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikú
ipa ọ̀nà rẹ̀ sọ́dọ̀ àwọn òkú. 19Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padà
bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í dé ọ̀nà ìyè. 20Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere
kí ìwọ kí ó sì pa ọ̀nà àwọn olódodo mọ́. 21Nítorí ẹni dídúró ṣinṣin yóò gbé ní ilé náà
àwọn aláìlẹ́gàn sì ni yóò máa wà nínú rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.