Òwe 1:3
Proverbs 1:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Láti gba ẹ̀kọ́ ọgbọ́n, òdodo, àti ìdájọ́, àti àìṣègbè;
Proverbs 1:3 in English
Proverbs 1:3 · Berean Standard Bible
and for receiving instruction in wise living and in righteousness, justice, and equity.
Context
1Àwọn òwe ti Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli. 2Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́,
láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀. 3Láti gba ẹ̀kọ́ ọgbọ́n, òdodo,
àti ìdájọ́, àti àìṣègbè; 4láti fi òye fún onírẹ̀lẹ̀,
ìmọ̀ àti ìṣọ́ra fún àwọn èwe. 5Jẹ́ kí ọlọ́gbọ́n tẹ́tí kí ó sì ní ìmọ̀ kún ìmọ̀,
sì jẹ́ kí ẹni òye gba ìtọ́sọ́nà.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.