Native Bible

Proverbs 1:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn òwe ti Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli.

Proverbs 1:1 in English

Proverbs 1:1 · Berean Standard Bible

These are the proverbs of Solomon son of David, king of Israel,

Context

1Àwọn òwe ti Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli. 2Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́, láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀. 3Láti gba ẹ̀kọ́ ọgbọ́n, òdodo, àti ìdájọ́, àti àìṣègbè;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.