Native Bible

Proverbs 1:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́, láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀.

Proverbs 1:2 in English

Proverbs 1:2 · Berean Standard Bible

for gaining wisdom and discipline, for comprehending words of insight,

Context

1Àwọn òwe ti Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli. 2Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́, láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀. 3Láti gba ẹ̀kọ́ ọgbọ́n, òdodo, àti ìdájọ́, àti àìṣègbè; 4láti fi òye fún onírẹ̀lẹ̀, ìmọ̀ àti ìṣọ́ra fún àwọn èwe.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.