Numeri 6:25
Numbers 6:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín.
Numbers 6:25 in English
Numbers 6:25 · Berean Standard Bible
may the LORD cause His face to shine upon you and be gracious to you;
Context
23“Sọ fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Báyìí ni kí ẹ ṣe máa súre fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹ sọ fún wọn pé, 24“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín,
kí ó sì pa yín mọ́. 25Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára.
Kí ó sì ṣàánú fún un yín. 26Kí Olúwa bojú wò yín,
kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’ 27“Báyìí ni wọn ó ṣe fi orúkọ mi sára àwọn ọmọ Israẹli, Èmi ó sì bùkún wọn.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.