Native Bible

Numbers 6:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́.

Numbers 6:24 in English

Numbers 6:24 · Berean Standard Bible

‘May the LORD bless you and keep you;

Context

22Olúwa sọ fún Mose pé, 23“Sọ fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Báyìí ni kí ẹ ṣe máa súre fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹ sọ fún wọn pé, 24“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́. 25Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín. 26Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.