Native Bible

Numbers 6:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’

Numbers 6:26 in English

Numbers 6:26 · Berean Standard Bible

may the LORD lift up His countenance toward you and give you peace.’

Context

24“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́. 25Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín. 26Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’ 27“Báyìí ni wọn ó ṣe fi orúkọ mi sára àwọn ọmọ Israẹli, Èmi ó sì bùkún wọn.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.