Native Bible

Numbers 6:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Báyìí ni wọn ó ṣe fi orúkọ mi sára àwọn ọmọ Israẹli, Èmi ó sì bùkún wọn.”

Numbers 6:27 in English

Numbers 6:27 · Berean Standard Bible

So they shall put My name on the Israelites, and I will bless them.”

Context

25Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín. 26Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’ 27“Báyìí ni wọn ó ṣe fi orúkọ mi sára àwọn ọmọ Israẹli, Èmi ó sì bùkún wọn.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.