Native Bible

Numbers 4:40 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Iye wọn nípa ìdílé àti ilé baba wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá ó lé ọgbọ̀n (2,630).

Numbers 4:40 in English

Numbers 4:40 · Berean Standard Bible

And those numbered by their clans and families totaled 2,630.

Context

38Wọ́n ka àwọn ọmọ Gerṣoni nípa ìdílé àti ilé baba wọn. 39Gbogbo ọmọkùnrin láti ọmọ ọgbọ̀n ọdún títí dé àádọ́ta, gbogbo àwọn tó lè ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé. 40Iye wọn nípa ìdílé àti ilé baba wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá ó lé ọgbọ̀n (2,630). 41Èyí jẹ́ àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Gerṣoni, àwọn tó ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé. Mose àti Aaroni ṣe bí àṣẹ Olúwa. 42Wọ́n ka àwọn ọmọ Merari nípa ìdílé àti ilé baba wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.