Numeri 4:42
Numbers 4:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n ka àwọn ọmọ Merari nípa ìdílé àti ilé baba wọn.
Numbers 4:42 in English
Numbers 4:42 · Berean Standard Bible
And the Merarites were numbered by their clans and families,
Context
40Iye wọn nípa ìdílé àti ilé baba wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá ó lé ọgbọ̀n (2,630). 41Èyí jẹ́ àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Gerṣoni, àwọn tó ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé. Mose àti Aaroni ṣe bí àṣẹ Olúwa. 42Wọ́n ka àwọn ọmọ Merari nípa ìdílé àti ilé baba wọn. 43Gbogbo ọkùnrin láti ọmọ ọgbọ̀n ọdún títí dé àádọ́ta ọdún, àwọn tó ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé. 44Iye wọn nípa ìdílé àti ilé baba wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rìndínlógún (3,200).
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.