Native Bible

Numbers 34:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Elisafani ọmọ Parnaki, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Sebuluni;

Numbers 34:25 in English

Numbers 34:25 · Berean Standard Bible

Eli-zaphan son of Parnach, a leader from the tribe of Zebulun;

Context

23Hannieli ọmọ Efodu, láti ẹ̀yà Manase, olórí àwọn ọmọ Josẹfu, 24Kemueli ọmọ Ṣiftani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Efraimu, ọmọ Josẹfu; 25Elisafani ọmọ Parnaki, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Sebuluni; 26Paltieli ọmọ Assani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Isakari; 27Ahihudu ọmọ Ṣelomi, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Aṣeri;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.