Native Bible

Numbers 34:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ahihudu ọmọ Ṣelomi, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Aṣeri;

Numbers 34:27 in English

Numbers 34:27 · Berean Standard Bible

Ahihud son of Shelomi, a leader from the tribe of Asher;

Context

25Elisafani ọmọ Parnaki, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Sebuluni; 26Paltieli ọmọ Assani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Isakari; 27Ahihudu ọmọ Ṣelomi, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Aṣeri; 28Pedaheli ọmọ Ammihudu, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Naftali.” 29Èyí ni àwọn ẹni tí Olúwa yàn láti pín ogún náà fún àwọn ọmọ Israẹli ní ilẹ̀ Kenaani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.