Native Bible

Numbers 34:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Pedaheli ọmọ Ammihudu, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Naftali.”

Numbers 34:28 in English

Numbers 34:28 · Berean Standard Bible

and Pedahel son of Ammihud, a leader from the tribe of Naphtali.”

Context

26Paltieli ọmọ Assani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Isakari; 27Ahihudu ọmọ Ṣelomi, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Aṣeri; 28Pedaheli ọmọ Ammihudu, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Naftali.” 29Èyí ni àwọn ẹni tí Olúwa yàn láti pín ogún náà fún àwọn ọmọ Israẹli ní ilẹ̀ Kenaani.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.