Native Bible

Numbers 34:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Hannieli ọmọ Efodu, láti ẹ̀yà Manase, olórí àwọn ọmọ Josẹfu,

Numbers 34:23 in English

Numbers 34:23 · Berean Standard Bible

Hanniel son of Ephod, a leader from the tribe of Manasseh son of Joseph;

Context

21Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini; 22Bukki ọmọ Jogli, láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dani; 23Hannieli ọmọ Efodu, láti ẹ̀yà Manase, olórí àwọn ọmọ Josẹfu, 24Kemueli ọmọ Ṣiftani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Efraimu, ọmọ Josẹfu; 25Elisafani ọmọ Parnaki, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ Sebuluni;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.