Native Bible

Numbers 34:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Bukki ọmọ Jogli, láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dani;

Numbers 34:22 in English

Numbers 34:22 · Berean Standard Bible

Bukki son of Jogli, a leader from the tribe of Dan;

Context

20Ṣemueli ọmọ Ammihudu, láti ẹ̀yà Simeoni; 21Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini; 22Bukki ọmọ Jogli, láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dani; 23Hannieli ọmọ Efodu, láti ẹ̀yà Manase, olórí àwọn ọmọ Josẹfu, 24Kemueli ọmọ Ṣiftani, olórí ẹ̀yà àwọn ọmọ, Efraimu, ọmọ Josẹfu;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.