Native Bible

Numbers 34:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣemueli ọmọ Ammihudu, láti ẹ̀yà Simeoni;

Numbers 34:20 in English

Numbers 34:20 · Berean Standard Bible

Shemuel son of Ammihud from the tribe of Simeon;

Context

18Kí o sì yan olórí kan nínú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti pín ilẹ̀ náà. 19“Èyí ni orúkọ wọn: “Kalebu ọmọ Jefunne, láti ẹ̀yà Juda; 20Ṣemueli ọmọ Ammihudu, láti ẹ̀yà Simeoni; 21Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini; 22Bukki ọmọ Jogli, láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dani;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.