Native Bible

Numbers 34:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Èyí ni orúkọ wọn: “Kalebu ọmọ Jefunne, láti ẹ̀yà Juda;

Numbers 34:19 in English

Numbers 34:19 · Berean Standard Bible

These are their names: Caleb son of Jephunneh from the tribe of Judah;

Context

17“Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin náà tí yóò pín ilẹ̀, náà fún yín gẹ́gẹ́ bí ogún: Eleasari àlùfáà àti Joṣua ọmọ Nuni. 18Kí o sì yan olórí kan nínú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti pín ilẹ̀ náà. 19“Èyí ni orúkọ wọn: “Kalebu ọmọ Jefunne, láti ẹ̀yà Juda; 20Ṣemueli ọmọ Ammihudu, láti ẹ̀yà Simeoni; 21Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.