Native Bible

Numbers 34:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini;

Numbers 34:21 in English

Numbers 34:21 · Berean Standard Bible

Elidad son of Chislon from the tribe of Benjamin;

Context

19“Èyí ni orúkọ wọn: “Kalebu ọmọ Jefunne, láti ẹ̀yà Juda; 20Ṣemueli ọmọ Ammihudu, láti ẹ̀yà Simeoni; 21Elidadi ọmọ Kisloni, láti ẹ̀yà Benjamini; 22Bukki ọmọ Jogli, láti ẹ̀yà olórí àwọn ọmọ Dani; 23Hannieli ọmọ Efodu, láti ẹ̀yà Manase, olórí àwọn ọmọ Josẹfu,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.