Numeri 33:13
Numbers 33:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n kúrò ní Dofka wọ́n sì pàgọ́ ní Aluṣi.
Numbers 33:13 in English
Numbers 33:13 · Berean Standard Bible
They set out from Dophkah and camped at Alush.
Context
11Wọ́n kúrò ní ẹ̀bá Òkun Pupa wọ́n sì pàgọ́ sínú aginjù Sini. 12Wọ́n kúrò nínú aginjù Sini wọ́n sì pàgọ́ sí aginjù Dofka. 13Wọ́n kúrò ní Dofka wọ́n sì pàgọ́ ní Aluṣi. 14Wọ́n kúrò ní Aluṣi wọ́n sì pàgọ́ ní Refidimu níbi tí kò sí omi fún àwọn ènìyàn náà láti mu. 15Wọ́n kúrò ní Refidimu wọ́n sì pàgọ́ ní aginjù Sinai.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.