Native Bible

Numbers 33:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n kúrò nínú aginjù Sini wọ́n sì pàgọ́ sí aginjù Dofka.

Numbers 33:12 in English

Numbers 33:12 · Berean Standard Bible

They set out from the Desert of Sin and camped at Dophkah.

Context

10Wọ́n kúrò ní Elimu wọ́n sì pàgọ́ sí ẹ̀bá Òkun Pupa. 11Wọ́n kúrò ní ẹ̀bá Òkun Pupa wọ́n sì pàgọ́ sínú aginjù Sini. 12Wọ́n kúrò nínú aginjù Sini wọ́n sì pàgọ́ sí aginjù Dofka. 13Wọ́n kúrò ní Dofka wọ́n sì pàgọ́ ní Aluṣi. 14Wọ́n kúrò ní Aluṣi wọ́n sì pàgọ́ ní Refidimu níbi tí kò sí omi fún àwọn ènìyàn náà láti mu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.