Native Bible

Numbers 33:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n kúrò ní Refidimu wọ́n sì pàgọ́ ní aginjù Sinai.

Numbers 33:15 in English

Numbers 33:15 · Berean Standard Bible

They set out from Rephidim and camped in the Wilderness of Sinai.

Context

13Wọ́n kúrò ní Dofka wọ́n sì pàgọ́ ní Aluṣi. 14Wọ́n kúrò ní Aluṣi wọ́n sì pàgọ́ ní Refidimu níbi tí kò sí omi fún àwọn ènìyàn náà láti mu. 15Wọ́n kúrò ní Refidimu wọ́n sì pàgọ́ ní aginjù Sinai. 16Wọ́n kúrò ní aginjù Sinai wọ́n sì pàgọ́ ní Kibirotu-Hattaafa. 17Wọ́n kúrò ní Kibirotu-Hattaafa wọ́n sì pàgọ́ ní Haserotu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.