Numeri 27:6
Numbers 27:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa sì wí fún un pé,
Numbers 27:6 in English
Numbers 27:6 · Berean Standard Bible
and the LORD answered him,
Context
4Kín ni ó dé tí orúkọ baba wa yóò parẹ́ nínú ìdílé rẹ̀ nítorí pé kò ní ọmọkùnrin? Fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrín àwọn arákùnrin baba wa.” 5Nígbà náà Mose mú ọ̀rọ̀ wọn wá síwájú Olúwa. 6Olúwa sì wí fún un pé, 7“Ohun tí àwọn ọmọbìnrin Selofehadi ń sọ tọ̀nà. O gbọdọ̀ fún wọn ní ogún ìní ti baba wọn. 8“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli, ‘Tí ọkùnrin kan bá kú tí kò sì fi ọmọkùnrin sáyé, ẹ fún àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ ní ogún ìní rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.