Numeri 27:5
Numbers 27:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà náà Mose mú ọ̀rọ̀ wọn wá síwájú Olúwa.
Numbers 27:5 in English
Numbers 27:5 · Berean Standard Bible
So Moses brought their case before the LORD,
Context
3“Baba wa kú sí aginjù. Kò sí lára àwọn ẹgbẹ́ Kora tí wọ́n kó ara wọn pọ̀ lòdì sí Olúwa, ṣùgbọ́n ó kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kò sì fi ọmọkùnrin sílẹ̀. 4Kín ni ó dé tí orúkọ baba wa yóò parẹ́ nínú ìdílé rẹ̀ nítorí pé kò ní ọmọkùnrin? Fún wa ní ilẹ̀ ìní láàrín àwọn arákùnrin baba wa.” 5Nígbà náà Mose mú ọ̀rọ̀ wọn wá síwájú Olúwa. 6Olúwa sì wí fún un pé, 7“Ohun tí àwọn ọmọbìnrin Selofehadi ń sọ tọ̀nà. O gbọdọ̀ fún wọn ní ogún ìní ti baba wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.