Native Bible

Numbers 13:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

láti inú ẹ̀yà Simeoni, Ṣafati ọmọ Hori;

Numbers 13:5 in English

Numbers 13:5 · Berean Standard Bible

from the tribe of Simeon, Shaphat son of Hori;

Context

3Mose sì rán wọn jáde láti aginjù Parani gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa. Gbogbo wọn jẹ́ olórí àwọn ènìyàn Israẹli. 4Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Reubeni, Ṣammua ọmọ Sakkuri; 5láti inú ẹ̀yà Simeoni, Ṣafati ọmọ Hori; 6láti inú ẹ̀yà Juda, Kalebu ọmọ Jefunne; 7láti inú ẹ̀yà Isakari, Igali ọmọ Josẹfu;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.