Native Bible

Numbers 13:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Reubeni, Ṣammua ọmọ Sakkuri;

Numbers 13:4 in English

Numbers 13:4 · Berean Standard Bible

and these were their names: From the tribe of Reuben, Shammua son of Zaccur;

Context

2“Rán ènìyàn díẹ̀ láti lọ yẹ ilẹ̀ Kenaani wò èyí tí mo ti fún àwọn ọmọ Israẹli. Rán ẹnìkọ̀ọ̀kan, tí ó jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan.” 3Mose sì rán wọn jáde láti aginjù Parani gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa. Gbogbo wọn jẹ́ olórí àwọn ènìyàn Israẹli. 4Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Reubeni, Ṣammua ọmọ Sakkuri; 5láti inú ẹ̀yà Simeoni, Ṣafati ọmọ Hori; 6láti inú ẹ̀yà Juda, Kalebu ọmọ Jefunne;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.