Native Bible

Numbers 13:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

láti inú ẹ̀yà Juda, Kalebu ọmọ Jefunne;

Numbers 13:6 in English

Numbers 13:6 · Berean Standard Bible

from the tribe of Judah, Caleb son of Jephunneh;

Context

4Orúkọ wọn nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Reubeni, Ṣammua ọmọ Sakkuri; 5láti inú ẹ̀yà Simeoni, Ṣafati ọmọ Hori; 6láti inú ẹ̀yà Juda, Kalebu ọmọ Jefunne; 7láti inú ẹ̀yà Isakari, Igali ọmọ Josẹfu; 8láti inú ẹ̀yà Efraimu, Hosea ọmọ Nuni;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.