Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ní Hasari-Ṣuali, ní Beerṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀.

Nehemiah 11:27 in English

Nehemiah 11:27 · Berean Standard Bible

in Hazar-shual; in Beersheba and its villages;

Context

25Fún ìletò pẹ̀lú oko wọn, díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn Juda tí ń gbé Kiriati-Arba, àti àwọn ìletò agbègbè e rẹ̀, ní Diboni àti ìletò rẹ̀, ní Jekabseeli. 26Ní Jeṣua, ní Molada, ní Beti-Peleti 27ní Hasari-Ṣuali, ní Beerṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀. 28Ní Siklagi, ní Mekona àti àwọn ìletò rẹ̀, 29ní Ẹni-Rimoni, ní Sora, ní Jarmatu,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.