Nehemiah 11:26
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní Jeṣua, ní Molada, ní Beti-Peleti
Nehemiah 11:26 in English
Nehemiah 11:26 · Berean Standard Bible
in Jeshua, Moladah, and Beth-pelet;
Context
24Petahiah ọmọ Meṣesabeli, ọ̀kan nínú àwọn Sera ọmọ Juda ní aṣojú ọba nínú ohun gbogbo tí ó jẹ mọ́ ti àwọn ènìyàn náà. 25Fún ìletò pẹ̀lú oko wọn, díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn Juda tí ń gbé Kiriati-Arba, àti àwọn ìletò agbègbè e rẹ̀, ní Diboni àti ìletò rẹ̀, ní Jekabseeli. 26Ní Jeṣua, ní Molada, ní Beti-Peleti 27ní Hasari-Ṣuali, ní Beerṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀. 28Ní Siklagi, ní Mekona àti àwọn ìletò rẹ̀,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.