Nehemiah 11:28
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní Siklagi, ní Mekona àti àwọn ìletò rẹ̀,
Nehemiah 11:28 in English
Nehemiah 11:28 · Berean Standard Bible
in Ziklag; in Meconah and its villages;
Context
26Ní Jeṣua, ní Molada, ní Beti-Peleti 27ní Hasari-Ṣuali, ní Beerṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀. 28Ní Siklagi, ní Mekona àti àwọn ìletò rẹ̀, 29ní Ẹni-Rimoni, ní Sora, ní Jarmatu, 30Sanoa, Adullamu àti àwọn ìletò o wọn, ní Lakiṣi àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Aseka àti àwọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Beerṣeba títí dé àfonífojì Hinnomu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.