Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ní Ẹni-Rimoni, ní Sora, ní Jarmatu,

Nehemiah 11:29 in English

Nehemiah 11:29 · Berean Standard Bible

in En-rimmon, Zorah, Jarmuth,

Context

27ní Hasari-Ṣuali, ní Beerṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀. 28Ní Siklagi, ní Mekona àti àwọn ìletò rẹ̀, 29ní Ẹni-Rimoni, ní Sora, ní Jarmatu, 30Sanoa, Adullamu àti àwọn ìletò o wọn, ní Lakiṣi àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Aseka àti àwọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Beerṣeba títí dé àfonífojì Hinnomu. 31Àwọn ọmọ Benjamini láti Geba ń gbé ní Mikmasi, Aija, Beteli àti àwọn ìletò rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.