Lefitiku 14:55
Leviticus 14:55 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àti fún ẹ̀tẹ̀ nínú aṣọ, àti ti ilé,
Leviticus 14:55 in English
Leviticus 14:55 · Berean Standard Bible
for mildew in clothing or in a house,
Context
53Kí àlùfáà ju ààyè ẹyẹ náà sílẹ̀ lẹ́yìn ìlú. Báyìí ni yóò ṣe ètùtù fún ilé náà. Ilé náà yóò sì mọ́.” 54Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún èyíkéyìí ààrùn àwọ̀ ara tí ó le è ràn ká, fún làpálàpá, 55àti fún ẹ̀tẹ̀ nínú aṣọ, àti ti ilé, 56fún ara wíwú, fún èélá àti ibi ara tí ó ń dán yàtọ̀. 57Láti mú kí a mọ̀ bóyá nǹkan mọ́ tàbí kò mọ́.
Ìwọ̀nyí ni àwọn òfin fún ààrùn àwọ̀ ara tí ó ń ràn ká àti ẹ̀tẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.