Lefitiku 14:54
Leviticus 14:54 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún èyíkéyìí ààrùn àwọ̀ ara tí ó le è ràn ká, fún làpálàpá,
Leviticus 14:54 in English
Leviticus 14:54 · Berean Standard Bible
This is the law for any infectious skin disease, for a scaly outbreak,
Context
52Yóò fi ẹ̀jẹ̀ ẹyẹ náà, omi tí ó mọ́, ààyè ẹyẹ, igi kedari, hísópù àti òdòdó sọ ilé náà di mímọ́. 53Kí àlùfáà ju ààyè ẹyẹ náà sílẹ̀ lẹ́yìn ìlú. Báyìí ni yóò ṣe ètùtù fún ilé náà. Ilé náà yóò sì mọ́.” 54Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún èyíkéyìí ààrùn àwọ̀ ara tí ó le è ràn ká, fún làpálàpá, 55àti fún ẹ̀tẹ̀ nínú aṣọ, àti ti ilé, 56fún ara wíwú, fún èélá àti ibi ara tí ó ń dán yàtọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.