Native Bible

Leviticus 14:57 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti mú kí a mọ̀ bóyá nǹkan mọ́ tàbí kò mọ́. Ìwọ̀nyí ni àwọn òfin fún ààrùn àwọ̀ ara tí ó ń ràn ká àti ẹ̀tẹ̀.

Leviticus 14:57 in English

Leviticus 14:57 · Berean Standard Bible

to determine when something is clean or unclean. This is the law regarding skin diseases and mildew.*”

Context

55àti fún ẹ̀tẹ̀ nínú aṣọ, àti ti ilé, 56fún ara wíwú, fún èélá àti ibi ara tí ó ń dán yàtọ̀. 57Láti mú kí a mọ̀ bóyá nǹkan mọ́ tàbí kò mọ́. Ìwọ̀nyí ni àwọn òfin fún ààrùn àwọ̀ ara tí ó ń ràn ká àti ẹ̀tẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.