Joṣua 15:62
Joshua 15:62 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nibṣani, Ìlú Iyọ̀ àti En-Gedi: ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn.
Joshua 15:62 in English
Joshua 15:62 · Berean Standard Bible
Nibshan, the City of Salt, and En-gedi—six cities, along with their villages.
Context
60Kiriati-Baali (tí í ṣe, Kiriati-Jearimu) àti Rabba ìlú méjì àti ìletò wọn. 61Ní aginjù:
Beti-Araba, Middini, Sekaka, 62Nibṣani, Ìlú Iyọ̀ àti En-Gedi: ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn. 63Juda kò lè lé àwọn ọmọ Jebusi jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jerusalẹmu. Àwọn ará Jebusi sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Juda títí dí òní.
15.47 Òkun Mẹditarenia
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.