Joṣua 15:63
Joshua 15:63 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Juda kò lè lé àwọn ọmọ Jebusi jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jerusalẹmu. Àwọn ará Jebusi sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Juda títí dí òní. 15.47 Òkun Mẹditarenia
Joshua 15:63 in English
Joshua 15:63 · Berean Standard Bible
But the descendants of Judah could not drive out the Jebusites living in Jerusalem. So to this day the Jebusites live there among the descendants of Judah.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.