Native Bible

Joshua 15:61 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ní aginjù: Beti-Araba, Middini, Sekaka,

Joshua 15:61 in English

Joshua 15:61 · Berean Standard Bible

These were in the wilderness: Beth-arabah, Middin, Secacah,

Context

59Maarati, Beti-Anoti àti Eltekoni: ìlú mẹ́fà àti àwọn ìletò wọn. 60Kiriati-Baali (tí í ṣe, Kiriati-Jearimu) àti Rabba ìlú méjì àti ìletò wọn. 61Ní aginjù: Beti-Araba, Middini, Sekaka, 62Nibṣani, Ìlú Iyọ̀ àti En-Gedi: ìlú mẹ́fà àti ìletò wọn. 63Juda kò lè lé àwọn ọmọ Jebusi jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jerusalẹmu. Àwọn ará Jebusi sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Juda títí dí òní. 15.47 Òkun Mẹditarenia

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.