Jobu 31:12
Job 31:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé iná ní èyí tí ó jó dé ibi ìparun, tí ìbá sì fa gbòǹgbò ohun ìbísí mi gbogbo tu.
Job 31:12 in English
Job 31:12 · Berean Standard Bible
For it is a fire that burns down to Abaddon;* it would root out my entire harvest.
Context
10kí àyà mi kí ó lọ ọlọ fún ẹlòmíràn,
kí àwọn ẹlòmíràn kí ó tẹ̀ ara wọn ní ara rẹ̀. 11Nítorí pé yóò jẹ́ ohun ìtìjú àní,
ẹ̀ṣẹ̀ tí a ó ṣe onídàájọ́ rẹ̀. 12Nítorí pé iná ní èyí tí ó jó dé ibi ìparun,
tí ìbá sì fa gbòǹgbò ohun ìbísí mi gbogbo tu. 13“Tí mo bá sì ṣe àìka ọ̀ràn ìránṣẹ́kùnrin mi
tàbí ìránṣẹ́bìnrin mi sí,
nígbà tí wọ́n bá ń bá mi jà; 14kí ni èmi ó ha ṣe nígbà tí Ọlọ́run bá dìde?
Nígbà tí ó bá sì ṣe ìbẹ̀wò, ohùn kí ni èmi ó dá?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.