Jobu 28:12
Job 28:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣùgbọ́n níbo ni á ó gbé wá ọgbọ́n rí, níbo sì ni òye ń gbe?
Job 28:12 in English
Job 28:12 · Berean Standard Bible
But where can wisdom be found, and where does understanding dwell?
Context
10Ó sì la ipa odò ṣíṣàn nínú àpáta,
ojú inú rẹ̀ sì rí ohun iyebíye gbogbo. 11Ó sì ṣe ìṣàn odò kí ó má ṣe kún àkúnya,
ó sì mú ohun tí ó pamọ́ hàn jáde wá sí ìmọ́lẹ̀. 12Ṣùgbọ́n níbo ni á ó gbé wá ọgbọ́n rí,
níbo sì ni òye ń gbe? 13Ènìyàn kò mọ iye rẹ̀,
bẹ́ẹ̀ ni a kò le è rí i ní ilẹ̀ àwọn alààyè. 14Ọ̀gbun wí pé, “Kò sí nínú mi”;
omi òkun sì wí pé, “Kò si nínú mi.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.