Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú,

Isaiah 3:19 in English

Isaiah 3:19 · Berean Standard Bible

their pendants, bracelets, and veils;

Context

17Nítorí náà Olúwa yóò mú egbò wá sórí àwọn obìnrin Sioni, Olúwa yóò sì pá wọn ní agbárí.” 18Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò já ọ̀ṣọ́ wọn gbà kúrò ti ọwọ́ àti gèlè àti ẹ̀gbà ọrùn tí ó dàbí òṣùpá 19gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú, 20gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn, 21òrùka ọwọ́ àti ti imú,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.