Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn,

Isaiah 3:20 in English

Isaiah 3:20 · Berean Standard Bible

their headdresses, ankle chains, and sashes; their perfume bottles and charms;

Context

18Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò já ọ̀ṣọ́ wọn gbà kúrò ti ọwọ́ àti gèlè àti ẹ̀gbà ọrùn tí ó dàbí òṣùpá 19gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú, 20gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn, 21òrùka ọwọ́ àti ti imú, 22àwọn àtàtà aṣọ, àwọ̀lékè, agbádá àti àpamọ́wọ́,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.