Gẹnẹsisi 46:18
Genesis 46:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí Jakọbu bí nípasẹ̀ Silipa, ẹni tí Labani fi fún Lea ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́rìndínlógún lápapọ̀.
Genesis 46:18 in English
Genesis 46:18 · Berean Standard Bible
These are the sons of Jacob born to Zilpah—whom Laban gave to his daughter Leah—sixteen in all.
Context
16Àwọn ọmọkùnrin Gadi:
Sefoni, Haggi, Ṣuni, Esboni, Eri, Arodi, àti Areli. 17Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri:
Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn ni Sera.
Àwọn ọmọkùnrin Beriah:
Heberi àti Malkieli. 18Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí Jakọbu bí nípasẹ̀ Silipa, ẹni tí Labani fi fún Lea ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́rìndínlógún lápapọ̀. 19Àwọn ọmọkùnrin Rakeli aya Jakọbu:
Josẹfu àti Benjamini. 20Ní Ejibiti, Asenati ọmọbìnrin Potifẹra, alábojútó àti àlùfáà Oni, bí Manase àti Efraimu fún Josẹfu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.