Gẹnẹsisi 46:19
Genesis 46:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọkùnrin Rakeli aya Jakọbu: Josẹfu àti Benjamini.
Genesis 46:19 in English
Genesis 46:19 · Berean Standard Bible
The sons of Jacob’s wife Rachel: Joseph and Benjamin.
Context
17Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri:
Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn ni Sera.
Àwọn ọmọkùnrin Beriah:
Heberi àti Malkieli. 18Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí Jakọbu bí nípasẹ̀ Silipa, ẹni tí Labani fi fún Lea ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́rìndínlógún lápapọ̀. 19Àwọn ọmọkùnrin Rakeli aya Jakọbu:
Josẹfu àti Benjamini. 20Ní Ejibiti, Asenati ọmọbìnrin Potifẹra, alábojútó àti àlùfáà Oni, bí Manase àti Efraimu fún Josẹfu. 21Àwọn ọmọ Benjamini:
Bela, Bekeri, Aṣbeli, Gera, Naamani, Ehi, Roṣi, Mupimu, Huppimu àti Ardi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.