Gẹnẹsisi 46:16
Genesis 46:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọkùnrin Gadi: Sefoni, Haggi, Ṣuni, Esboni, Eri, Arodi, àti Areli.
Genesis 46:16 in English
Genesis 46:16 · Berean Standard Bible
The sons of Gad: Ziphion,* Haggi, Shuni, Ezbon, Eri, Arodi,* and Areli.
Context
14Àwọn ọmọkùnrin Sebuluni:
Seredi, Eloni àti Jahaleli. 15Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin Lea tí ó bí fún Jakọbu ní Padani-Aramu yàtọ̀ fún Dina ọmọbìnrin rẹ̀. Àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ àti ọmọbìnrin rẹ̀ wọ̀nyí jẹ́ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) lápapọ̀. 16Àwọn ọmọkùnrin Gadi:
Sefoni, Haggi, Ṣuni, Esboni, Eri, Arodi, àti Areli. 17Àwọn ọmọkùnrin Aṣeri:
Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn ni Sera.
Àwọn ọmọkùnrin Beriah:
Heberi àti Malkieli. 18Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí Jakọbu bí nípasẹ̀ Silipa, ẹni tí Labani fi fún Lea ọmọbìnrin rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́rìndínlógún lápapọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.