Gẹnẹsisi 2:12
Genesis 2:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
(Wúrà ilẹ̀ náà dára, òjìá* àti òkúta óníkìsì oníyebíye wà níbẹ̀ pẹ̀lú).
Genesis 2:12 in English
Genesis 2:12 · Berean Standard Bible
And the gold of that land is pure, and bdellium and onyx are found there.
Context
10Odò kan sì ń ti Edeni sàn wá láti bu omi rin ọgbà náà, láti ibẹ̀ ni odò náà gbé ya sí ipa mẹ́rin. 11Orúkọ èkínní ni Pisoni, òun ni ó sàn yí gbogbo ilẹ̀ Hafila ká, níbi tí wúrà gbé wà. 12(Wúrà ilẹ̀ náà dára, òjìá* àti òkúta óníkìsì oníyebíye wà níbẹ̀ pẹ̀lú). 13Orúkọ odò kejì ni Gihoni, òun ni ó sàn yí gbogbo ilẹ̀ Kuṣi ká. 14Orúkọ odò kẹta ni Tigirisi, òun ni ó sàn ní apá ìlà-oòrùn ilẹ̀ Asiria. Odò kẹrin ni Eufurate.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.