Gẹnẹsisi 11:20
Genesis 11:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu.
Genesis 11:20 in English
Genesis 11:20 · Berean Standard Bible
When Reu was 32 years old, he became the father of Serug.
Context
18Nígbà tí Pelegi pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Reu. 19Pelegi sì tún wà láààyè fún igba ọdún ó lé mẹ́sàn-án (209) lẹ́yìn tí ó bí Reu, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn. 20Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu. 21Reu tún wà láààyè lẹ́yìn tí ó bí Serugu fún igba ọdún ó lé méje (207), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn. 22Nígbà tí Serugu pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.