Gẹnẹsisi 11:18
Genesis 11:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà tí Pelegi pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Reu.
Genesis 11:18 in English
Genesis 11:18 · Berean Standard Bible
When Peleg was 30 years old, he became the father of Reu.
Context
16Eberi sì jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n, ó sì bí Pelegi. 17Eberi sì wà láààyè fún irinwó ọdún ó lé ọgbọ̀n (430) lẹ́yìn tí ó bí Pelegi, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn. 18Nígbà tí Pelegi pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Reu. 19Pelegi sì tún wà láààyè fún igba ọdún ó lé mẹ́sàn-án (209) lẹ́yìn tí ó bí Reu, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn. 20Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.