Native Bible

Genesis 11:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Serugu pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori.

Genesis 11:22 in English

Genesis 11:22 · Berean Standard Bible

When Serug was 30 years old, he became the father of Nahor.

Context

20Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu. 21Reu tún wà láààyè lẹ́yìn tí ó bí Serugu fún igba ọdún ó lé méje (207), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn. 22Nígbà tí Serugu pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori. 23Serugu sì wà láààyè fún igba ọdún lẹ́yìn tí ó bí Nahori, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn. 24Nígbà tí Nahori pé ọmọ ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n, ó bí Tẹra.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.