Native Bible

Genesis 11:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Arfakṣadi pé ọdún márùndínlógójì ni ó bí Ṣela.

Genesis 11:12 in English

Genesis 11:12 · Berean Standard Bible

When Arphaxad was 35 years old, he became the father of Shelah.

Context

10Wọ̀nyí ni ìran Ṣemu. Ọdún méjì lẹ́yìn ìkún omi, tí Ṣemu pé ọgọ́rùn-ún ọdún ni ó bí Arfakṣadi. 11Lẹ́yìn tí ó bí Arfakṣadi, Ṣemu tún wà láààyè fún ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ọdún (500), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn. 12Nígbà tí Arfakṣadi pé ọdún márùndínlógójì ni ó bí Ṣela. 13Arfakṣadi sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ṣela, ó sì bí àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ọmọkùnrin mìíràn. 14Nígbà tí Ṣela pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Eberi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.