Native Bible

Genesis 11:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Ṣela pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Eberi.

Genesis 11:14 in English

Genesis 11:14 · Berean Standard Bible

When Shelah was 30 years old, he became the father of Eber.

Context

12Nígbà tí Arfakṣadi pé ọdún márùndínlógójì ni ó bí Ṣela. 13Arfakṣadi sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ṣela, ó sì bí àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ọmọkùnrin mìíràn. 14Nígbà tí Ṣela pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Eberi. 15Ṣela sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Eberi tán, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn. 16Eberi sì jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n, ó sì bí Pelegi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.